Se ileeṣẹ Ọlọpaa Naijira dabii gbogbo ileeṣẹ to ku ni? Bii gbogbo ileeṣẹ ọlọpaa kaakiri agbaye, iṣẹ nla l'awọn ọlọpaa Naijiria pẹlu n ṣe lati daabo bo ẹmi ati dukia araalu. Bẹẹni kii ṣe owo oṣu kekere ...