Ileeṣẹ apinaka ni ipinlẹ Eko, Ikeja Electric Distribution Company, IKEDC, ti sọ pe awọn ko tii bẹrẹ si ni gba idiyele owo ina tuntun lọwọ awọn onibara wọn. Alukoro ileeṣẹ naa, Felix Ofulue lo kede bẹẹ ...